Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Alẹ́ ti lẹ́ tipẹ́. Ilẹ̀ fẹ́rẹ̀ mọ́. Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á pa iṣẹ́ òkùnkùn tì, kí á múra gẹ́gẹ́ bí ọmọ-ogun ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Romu 13

Wo Romu 13:12 ni o tọ