Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ bí ìṣìnà wọn bá ṣe ayé ní anfaani, bí ìkùnà wọn bá ṣe orílẹ̀-èdè yòókù ní anfaani, báwo ni anfaani náà yóo ti pọ̀ tó nígbà tí gbogbo wọn bá ṣe ojúṣe wọn?

Ka pipe ipin Romu 11

Wo Romu 11:12 ni o tọ