Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ìyìn rere yìí ni a ti ń fi ọ̀nà tí Ọlọrun fi ń dá eniyan láre hàn wá: nípa igbagbọ ni, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin. Gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Nítorí igbagbọ ni ẹni tí a bá dá láre yóo fi yè.”

Ka pipe ipin Romu 1

Wo Romu 1:17 ni o tọ