Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú kò tì mí láti waasu ìyìn rere Jesu, nítorí ìyìn rere yìí ni agbára Ọlọrun, tí a fi ń gba gbogbo àwọn tí ó bá gbà á gbọ́ là. Ó kọ́kọ́ lo agbára yìí láàrin àwọn Juu, lẹ́yìn náà ó lò ó láàrin àwọn Giriki.

Ka pipe ipin Romu 1

Wo Romu 1:16 ni o tọ