Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí rẹ̀ ni a ṣe waasu ìyìn rere fún àwọn òkú, pé bí wọ́n bá tilẹ̀ gba ìdájọ́ bí gbogbo eniyan ti níláti gbà ninu ara, sibẹ wọn óo wà láàyè ninu ẹ̀mí nípa ti Ọlọrun.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 4

Wo Peteru Kinni 4:6 ni o tọ