Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìgbà kan rí ẹ ní anfaani tó láti ṣe àwọn ohun tí àwọn abọ̀rìṣà ń ṣe. Ẹ̀ ń hùwà wọ̀bìà, ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́, ìmutípara, ayé ìjẹkújẹ, ìmukúmu ati ìbọ̀rìṣà tí ó jẹ́ èèwọ̀.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 4

Wo Peteru Kinni 4:3 ni o tọ