Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó tó àkókò tí ìdájọ́ yóo bẹ̀rẹ̀, láàrin ìdílé Ọlọrun ni yóo sì ti bẹ̀rẹ̀. Tí ó bá wá bẹ̀rẹ̀ lọ́dọ̀ wa, báwo ni yóo ti rí fún àwọn tí kò gba ìyìn rere Ọlọrun gbọ́?

Ka pipe ipin Peteru Kinni 4

Wo Peteru Kinni 4:17 ni o tọ