Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Peteru Kinni 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ bá jìyà gẹ́gẹ́ bí onigbagbọ ẹ má jẹ́ kí ó tì yín lójú, kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa yin Ọlọrun lógo fún orúkọ tí ẹ̀ ń jẹ́.

Ka pipe ipin Peteru Kinni 4

Wo Peteru Kinni 4:16 ni o tọ