Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí èyí ni mo ṣe sọ fun yín pé kí ẹ má máa ṣe àníyàn nípa ẹ̀mí yín, pé kí ni ẹ óo jẹ tabi kí ni ẹ óo mu, tabi pé kí ni ẹ óo fi bora. Mo ṣebí ẹ̀mí yín ju oúnjẹ lọ; ati pé ara yín ju aṣọ lọ.

Ka pipe ipin Matiu 6

Wo Matiu 6:25 ni o tọ