Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 6:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kò sí ẹni tí ó lè sin oluwa meji. Nítorí ọ̀kan ni yóo ṣe: ninu kí ó kórìíra ọ̀kan, kí ó fẹ́ràn ekeji, tabi kí ó fara mọ́ ọ̀kan, kí ó má ka ekeji sí. Ẹ kò lè sin Ọlọrun, kí ẹ tún máa bọ owó.

Ka pipe ipin Matiu 6

Wo Matiu 6:24 ni o tọ