Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu sọ fún un pé, “Ó tún wà ní àkọsílẹ̀ pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ dán Oluwa Ọlọrun rẹ wò.’ ”

Ka pipe ipin Matiu 4

Wo Matiu 4:7 ni o tọ