Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún un pé, “Bí Ọmọ Ọlọrun bá ni ọ́ nítòótọ́, bẹ́ sílẹ̀. Nítorí ó wà ní àkọsílẹ̀ pé,‘Yóo pàṣẹ fún àwọn angẹli rẹ̀ nítorí rẹ,kí wọ́n tẹ́wọ́ gbà ọ́,kí o má baà fi ẹsẹ̀ gbún òkúta.’ ”

Ka pipe ipin Matiu 4

Wo Matiu 4:6 ni o tọ