Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 4:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ eniyan ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn láti Galili ati Ìlú Mẹ́wàá ati Jerusalẹmu ati Judia, ati láti òdìkejì Jọdani.

Ka pipe ipin Matiu 4

Wo Matiu 4:25 ni o tọ