Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 4:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkìkí rẹ̀ kàn ká gbogbo Siria. Àwọn eniyan ń gbé gbogbo àwọn tí ó ní oríṣìíríṣìí àrùn ati àìlera wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ati àwọn tí ẹ̀mí Èṣù ń dà láàmú, ati àwọn tí wárápá mú ati àwọn arọ; ó sì ń wò wọ́n sàn.

Ka pipe ipin Matiu 4

Wo Matiu 4:24 ni o tọ