Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnìkan bá bi yín ní nǹkankan, ẹ dá a lóhùn pé, ‘Oluwa nílò wọn.’ Lẹsẹkẹsẹ wọn yóo jẹ́ kí ẹ mú wọn wá.”

Ka pipe ipin Matiu 21

Wo Matiu 21:3 ni o tọ