Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí ìletò tí ó wà ní ọ̀kánkán yín yìí. Bí ẹ bá ti wọ inú rẹ̀, ẹ óo rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan tí wọ́n so mọ́lẹ̀, pẹlu ọmọ rẹ̀. Ẹ tú wọn, kí ẹ mú wọn wá fún mi.

Ka pipe ipin Matiu 21

Wo Matiu 21:2 ni o tọ