Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 20:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ọjọ́ rọ̀, ẹni tí ó ni ọgbà àjàrà náà sọ fún iranṣẹ rẹ̀ pé, ‘Pe àwọn òṣìṣẹ́, kí o fún wọn ní owó wọn, bẹ̀rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn tí ó dé gbẹ̀yìn, títí dé ọ̀dọ̀ àwọn tí ó kọ́kọ́ dé.’

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:8 ni o tọ