Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 20:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, ‘Nítorí ẹnikẹ́ni kò gbà wá síṣẹ́ ni.’ Ó sọ fún wọn pé, ‘Ẹ̀yin náà ẹ lọ sinu ọgbà àjàrà mi.’

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:7 ni o tọ