Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá lọ, ó kó àwọn ẹ̀mí meje mìíràn lẹ́yìn tí wọ́n burú ju òun alára lọ, wọ́n bá wọlé, wọ́n ń gbé ibẹ̀. Ìgbẹ̀yìn ẹni náà wá burú ju ti àkọ́kọ́ lọ. Bẹ́ẹ̀ ni yóo rí fún ìran burúkú yìí.”

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:45 ni o tọ