Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá ni, ‘N óo tún pada sí ilé mi, níbi tí mo ti jáde kúrò.’ Nígbà tí ó débẹ̀, ó rí i pé ibẹ̀ ṣófo, ati pé a ti gbá a, a sì ti tọ́jú rẹ̀ dáradára.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:44 ni o tọ