Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Báwo ni ẹnìkan ṣe lè wọ ilé alágbára lọ, kí ó kó o lẹ́rù, bí kò bá kọ́kọ́ de alágbára náà? Bí ó bá kọ́kọ́ dè é ni yóo tó lè kó o lẹ́rù.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:29 ni o tọ