Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ pé nípa Ẹ̀mí Ọlọrun ni mo fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a jẹ́ pé ìjọba Ọlọrun ti dé ba yín.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:28 ni o tọ