Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu mọ ohun tí wọn ń rò. Ó bá sọ fún wọn pé, “Gbogbo ìjọba tí ó bá gbé ogun ti ara rẹ̀ yóo parun. Bẹ́ẹ̀ ni, gbogbo ìlúkílùú tabi ilékílé tí àwọn eniyan ibẹ̀ bá ń bá ara wọn jà yóo tú.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:25 ni o tọ