Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí àwọn Farisi gbọ́, wọ́n ní, “Ojú lásán kọ́ ni ọkunrin yìí fi ń lé ẹ̀mí èṣù jáde; agbára Beelisebulu, olórí àwọn ẹ̀mí èṣù ni ó ń lò.”

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:24 ni o tọ