Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 10:37 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹni tí ó bá fẹ́ràn baba tabi ìyá rẹ̀ jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi. Ẹni tí ó bá fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ ọkunrin tabi obinrin jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi.

Ka pipe ipin Matiu 10

Wo Matiu 10:37 ni o tọ