Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 6:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ Hẹrọdiasi obinrin bá wọlé, ó bọ́ sí agbo, ó bẹ̀rẹ̀ sí jó, inú Hẹrọdu ati ti àwọn tí ó wà níbi àsè náà dùn. Ọba sọ fún ọmọbinrin náà pé, “Bèèrè ohun tí o bá fẹ́, n óo fi í fún ọ.”

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:22 ni o tọ