Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 6:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ kan, Hẹrọdiasi rí àkókò tí ó wọ̀ láti ṣe ìfẹ́ rẹ̀. Hẹrọdu se àsè ọjọ́ ìbí rẹ̀, ó pe àwọn ìjòyè, àwọn ọ̀gágun, ati àwọn eniyan pataki ilẹ̀ Galili.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:21 ni o tọ