Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀pọ̀ eniyan bá wá péjọ sibẹ, wọ́n pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ó fi jẹ́ pé ati inú ilé, ati ẹnu ọ̀nà ni ó kún. Ó bá ń sọ̀rọ̀ ìyìn rere fún wọn.

Ka pipe ipin Maku 2

Wo Maku 2:2 ni o tọ