Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, Jesu tún lọ sí Kapanaumu, àwọn eniyan gbọ́ pé ó wà ninu ilé kan.

Ka pipe ipin Maku 2

Wo Maku 2:1 ni o tọ