Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 14:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kinni Àjọ̀dún Àìwúkàrà, ní ọjọ́ tí wọn máa ń pa aguntan láti ṣe Àjọ̀dún Ìrékọjá, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu bi í pé, “Níbo ni o fẹ́ kí á tọ́jú fún ọ láti jẹ àsè Ìrékọjá?”

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:12 ni o tọ