Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́ ohun tí ó bá wá, inú wọn dùn, wọ́n bá ṣe ìlérí láti fún un ní owó. Judasi wá ń wá àkókò tí ó wọ̀ láti fi Jesu lé wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Maku 14

Wo Maku 14:11 ni o tọ