Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ẹ̀yin fúnra yín, ẹ kíyèsára. Wọn yóo fà yín lọ siwaju àwọn ìgbìmọ̀. Wọn yóo lù yín ninu àwọn ilé ìpàdé. Wọn yóo mu yín lọ siwaju àwọn aláṣẹ ati àwọn ọba nítorí mi kí ẹ lè jẹ́rìí ìyìn rere fún wọn.

Ka pipe ipin Maku 13

Wo Maku 13:9 ni o tọ