Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:38 BIBELI MIMỌ (BM)

ó lọ dúró lẹ́yìn lẹ́bàá ẹsẹ̀ Jesu, ó ń sunkún, omijé rẹ̀ ń dà sí ẹsẹ̀ Jesu, ó bẹ̀rẹ̀ sí fi irun rẹ̀ nù ún, ó ń fi ẹnu kan ẹsẹ̀ Jesu, ó tún ń fi òróró kùn ún lẹ́sẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:38 ni o tọ