Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 7:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin kan báyìí wà ninu ìlú tí ó gbọ́ pé Jesu ń jẹun ní ilé Farisi, ó mú ìgò òróró olóòórùn dídùn lọ́wọ́,

Ka pipe ipin Luku 7

Wo Luku 7:37 ni o tọ