Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ó sọ fún wọn pé, “Dandan ni fún mi láti waasu ìyìn rere ìjọba ọ̀run ní àwọn ìlú mìíràn, nítorí ohun tí Ọlọrun rán mi wá ṣe nìyí.”

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:43 ni o tọ