Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, Jesu jáde lọ sí ẹ̀yìn odi ìlú níbi tí kò sí ẹnìkankan. Àwọn eniyan ń wá a kiri. Nígbà tí wọ́n rí i, wọ́n fẹ́ dá a dúró kí ó má kúrò lọ́dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:42 ni o tọ