Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá lọ dúró lẹ́bàá ibùsùn ìyá náà, ó bá ibà náà wí, ibà sì fi ìyá náà sílẹ̀. Lẹsẹkẹsẹ ó dìde, ó bá tọ́jú oúnjẹ fún wọn.

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:39 ni o tọ