Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu dìde kúrò ní ilé ìpàdé, ó wọ ilé Simoni lọ. Ìyá iyawo Simoni ń ṣàìsàn akọ ibà. Wọ́n bá sọ fún Jesu.

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:38 ni o tọ