Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu ya gbogbo eniyan. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí sọ láàrin ara wọn pé, “Irú ọ̀rọ̀ wo ni èyí? Nítorí pẹlu àṣẹ ati agbára ni ó fi bá àwọn ẹ̀mí èṣù wí, wọ́n sì ń jáde!”

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:36 ni o tọ