Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá bá a wí, ó ní, “Pa ẹnu mọ́, kí o jáde kúrò ninu ọkunrin yìí!” Ẹ̀mí èṣù náà bá gbé ọkunrin náà ṣánlẹ̀ lójú gbogbo wọn, ó bá jáde kúrò lára rẹ̀, láì pa á lára.

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:35 ni o tọ