Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan, Johanu bá Hẹrọdu baálẹ̀ wí nítorí ọ̀ràn Hẹrọdiasi, iyawo Filipi, arakunrin rẹ̀, tí Hẹrọdu gbà. Ó tún bá a wí fún gbogbo nǹkan burúkú mìíràn tí ó ṣe.

Ka pipe ipin Luku 3

Wo Luku 3:19 ni o tọ