Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu kígbe, ó ní, “Baba, ní ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé.” Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, ó mí kanlẹ̀, ó bá kú.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:46 ni o tọ