Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:44-45 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tó bí agogo mejila ọ̀sán, òkùnkùn bo gbogbo ilẹ̀ títí di agogo mẹta ọ̀sán. Oòrùn kò ràn. Aṣọ ìkélé Tẹmpili ya sí meji.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:44-45 ni o tọ