Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 22:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Jesu ti ń sọ̀rọ̀ ni àwọn eniyan bá dé. Judasi, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn, ni ó ṣiwaju wọn. Ó bá súnmọ́ Jesu, ó fi ẹnu kò ó ní ẹ̀rẹ̀kẹ́.

Ka pipe ipin Luku 22

Wo Luku 22:47 ni o tọ