Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 22:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wá sọ fún wọn pé, “Ṣugbọn ní àkókò yìí, ẹni tí ó bá ní àpò owó kí ó mú un lọ́wọ́; ẹni tí ó bá ní igbá báárà, kí òun náà gbé e lọ́wọ́. Ẹni tí kò bá ní idà, kí ó ta ẹ̀wù rẹ̀ kí ó fi ra idà kan.

Ka pipe ipin Luku 22

Wo Luku 22:36 ni o tọ