Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 22:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wá sọ fún wọn pé, “Nígbà tí mo ran yín níṣẹ́ tí mo sọ fun yín pé kí ẹ má mú àpò owó ati igbá báárà lọ́wọ́, ati pé kí ẹ má wọ bàtà, kí ni ohun tí ẹ ṣe aláìní?”Wọ́n dáhùn pé, “Kò sí!”

Ka pipe ipin Luku 22

Wo Luku 22:35 ni o tọ