Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọjọ́ kẹjọ pé láti kọ ọmọ náà ní ilà-abẹ́, wọ́n sọ orúkọ rẹ̀ ní Jesu, gẹ́gẹ́ bí angẹli ti wí, kí ìyá rẹ̀ tó lóyún rẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 2

Wo Luku 2:21 ni o tọ