Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olùṣọ́-aguntan náà pada síbi iṣẹ́ wọn, wọ́n ń fi ògo ati ìyìn fún Ọlọrun fún gbogbo nǹkan tí wọ́n gbọ́, ati àwọn nǹkan tí wọ́n rí gẹ́gẹ́ bí angẹli náà ti sọ fún wọn.

Ka pipe ipin Luku 2

Wo Luku 2:20 ni o tọ