Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ń gbé àwọn ọmọ-ọwọ́ wá, pé kí ó lè fi ọwọ́ kàn wọ́n. Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rí wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bá àwọn tí wọ́n gbé wọn wá wí.

Ka pipe ipin Luku 18

Wo Luku 18:15 ni o tọ