Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 18:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé agbowó-odè yìí lọ sí ilé rẹ̀ pẹlu ọkàn ìdáláre ju èyí Farisi lọ. Nítorí ẹni tí ó bá gbé ara rẹ̀ ga ni a óo rẹ̀ sílẹ̀; ẹni tí ó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ ni a óo gbé ga.”

Ka pipe ipin Luku 18

Wo Luku 18:14 ni o tọ